Genesis 41:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn mààlúù tí wọ́n rù wọnyi gbé àwọn tí wọ́n sanra mì.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn abo-malu ti o rù, ti nwọn si buru ni wiwò, nwọn mú awọn abo-malu meje sisanra iṣaju wọnni jẹ:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn màlúù tí ó rù tí kò sì lẹ́wà sì jẹ àwọn màlúù tí ó sanra tí ó kọ́ jáde nínú odò.