Genesis 41:37 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìmọ̀ràn náà dára lójú Farao ati àwọn iranṣẹ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ohun na si dara li oju Farao, ati li oju gbogbo awọn ọmọ-ọdọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èrò náà sì dára lójú Fáráò àti àwọn ìjòyè rẹ̀.