Genesis 46:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ ti Aṣeri ni: Imina, Iṣifa, Iṣifi, Beraya, ati Sera arabinrin wọn. Àwọn ọmọ ti Beraya ni Heberi, ati Malikieli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Aṣeri; Jimna, ati Iṣua, ati Isui, ati Beria, ati Sera arabinrin wọn: ati awọn ọmọ Beria; Heberi, ati Malkieli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọkùnrin Ásérì: Ímínà, Íṣífà, Íṣífì àti Béríà. Arábìnrin wọn ni Ṣérà. Àwọn ọmọkùnrin Béríà: Ébérì àti Málíkíélì.