Genesis 48:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó bá súre fún wọn ní ọjọ́ náà, ó ní, “Orúkọ yín ni Israẹli yóo fi máa súre fún eniyan, wọn yóo máa súre pé, ‘Kí Ọlọrun kẹ́ ọ bí ó ti kẹ́ Efuraimu ati Manase.’ ” Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe fi Efuraimu ṣáájú Manase.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si sure fun wọn li ọjọ́ na pe, Iwọ ni Israeli o ma fi sure, wipe, Ki Ọlọrun ki o ṣe nyin bi Efraimu on Manasse: bẹ̃li o fi Efraimu ṣaju Manasse.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó súre fún wọn lọ́jọ́ náà pé, “Ní orúkọ yín ni Ísírẹ́lì yóò máa súre yìí pé: ‘Kí Ọlọ́run ṣe ọ́ bí i ti Éfúráímù àti Mánásè.’ ”