Genesis 49:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn nígbà tí ó rí i pé ibi ìsinmi dára ati pé ilẹ̀ náà dára, ó tẹ́ ẹ̀yìn sílẹ̀ láti ru ẹrù, ó sì di ẹni tí wọn ń mú sìn bí ẹrú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ri pe isimi dara, ati ilẹ na pe o wuni; o si tẹ̀ ejiká rẹ̀ lati rẹrù, on si di ẹni nsìnrú.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ó bá rí bí ibi ìsinmi òun ti dára tó, àti bí ilẹ̀ rẹ̀ ti ní ìdẹ̀ra tó, yóò tẹ èjìká rẹ̀ ba láti ru àjàgà, yóò sì fi ara rẹ̀ fún iṣẹ́ ipá.
Recommended Reading