Genesis 49:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn olè yóo máa kó Gadi lẹ́rù, ṣugbọn bí wọ́n ti ń kó o, bẹ́ẹ̀ ni yóo sì máa gbà á pada.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gadi ọwọ́-ogun ni yio kọlù u: ṣugbọn on lé wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ẹgbẹ́-ogun àwọn ẹlẹ́sin yóò kọ lu Gádì, ṣùgbọ́n yóò kọ lu wọ́n ní gìgíṣẹ̀ wọn.