Genesis 49:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn tafàtafà gbógun tì í kíkankíkan, wọ́n ń ta á lọ́fà, wọ́n sì ń dà á láàmú gidigidi,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn tafàtafa bà a ninu jẹ́ pọ̀ju, nwọn si tafà si i, nwọn si korira rẹ̀:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pẹ̀lú ìkorò, àwọn tafàtafà dojú ìjà kọ ọ́, wọ́n tafà sí í pẹ̀lú ìkanra,