Genesis 49:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ibukun àwọn baba rẹ ju ti àwọn òkè ayérayé lọ, kí ibukun àwọn òkè ayérayé wá sórí Josẹfu, ẹni tí wọ́n yà ní ipá lọ́dọ̀ àwọn arakunrin rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ibukún baba rẹ ti jù ibukún awọn baba nla mi lọ, titi dé opin oke aiyeraiye wọnni: nwọn o si ma gbé ori Josefu, ati li atari ẹniti a yàsọtọ lãrin awọn arakunrin rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ìbùkún baba rẹ pọ̀ púpọ̀ ju ìbùkún àwọn òkè ńlá ìgbàanì, ju ẹ̀bùn ńlá àwọn òkè láéláé. Jẹ́ kí gbogbo èyí sọ̀kalẹ̀ sí orí Jóṣẹ́fù, lé ìpéǹpéjú ọmọ aládé láàrin arákùnrin rẹ̀.