Genesis 49:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Reubẹni, ìwọ ni àkọ́bí mi, agbára mi, ati àkọ́so èso agbára mi, ìwọ tí o ní ìgbéraga jùlọ, tí o sì lágbára jùlọ ninu àwọn ọmọ mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Reubeni, iwọ li akọ́bi mi, agbara mi, ati ipilẹṣẹ ipá mi, titayọ ọlá, ati titayọ agbara.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Rúbẹ́nì, ìwọ ni àkọ́bí mi, agbára mi, ìpìlẹṣẹ̀ ipá mi, títayọ ní ọlá àti títayọ ní agbára.