Genesis 5:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Enọku wà ní ìrẹ́pọ̀ pẹlu Ọlọrun, nígbà tí ó yá, wọn kò rí i mọ́ nítorí pé Ọlọrun mú un lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Enoku si ba Ọlọrun rìn: on kò si sí; nitori ti Ọlọrun mu u lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Énọ́kù bá Ọlọ́run rìn: a kò sì rí i mọ́ nítorí Ọlọ́run mú un lọ.