Genesis 50:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Jakọbu sin òkú rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ó ti pa á láṣẹ fún wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ rẹ̀ si ṣe bi o ti fi aṣẹ fun wọn:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Báyìí ni àwọn ọmọ Jákọ́bù ṣe ohun tí baba wọn páṣẹ fún wọn.