Genesis 9:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Noa mẹtẹẹta yìí ni baba ńlá gbogbo ayé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn mẹta wọnyi li ọmọ Noa: lati ọdọ wọn li a gbé ti tàn ká gbogbo aiye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nípaṣẹ̀ àwọn ọmọ Nóà mẹ́tẹ̀ẹ̀ta yìí ni gbogbo ènìyàn ti tàn ká gbogbo ilẹ̀ ayé.