Genesis 9:27 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí Ọlọrun sọ ìdílé Jafẹti di pupọ, kí ó máa gbé ninu àgọ́ Ṣemu, ẹrú rẹ̀ ni Kenaani yóo máa ṣe.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọlọrun yio mu Jafeti gbilẹ, yio si ma gbé agọ́ Ṣemu; Kenaani yio si ma ṣe iranṣẹ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọlọ́run yóò mú Jáfétì gbilẹ̀, Jáfétì yóò máa gbé ní àgọ́ Ṣémù Kénánì yóò sì jẹ́ ẹrú fún-un.”