Habakkuk 1:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí o ti jẹ́ kí ọmọ eniyan dàbí ẹja inú òkun, ati bí àwọn kòkòrò tí wọn ń rìn nílẹ̀, tí wọn kò ní olórí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti iwọ si nṣe enia bi ẹja okun, bi ohun ti nrakò, ti kò ni alakoso lori wọn?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ sì tí sọ ènìyàn di bí ẹja inú òkun, bí àwọn ẹ̀dá inú òkun tí wọn ko ni alákòóso