Habakkuk 1:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọ̀tá fi ìwọ̀ fa gbogbo wọn sókè, ó sì fi àwọ̀n rẹ̀ kó wọn jáde. Ó kó wọn papọ̀ sinu àwọ̀n rẹ̀, Nítorí náà ó ń yọ̀, inú rẹ̀ sì dùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ ni àwọn lati fi gbé gbogbo wọn, nwọn nfi àwọn mu wọn, nwọn si nfi awò wọn kó wọn: nitorina ni nwọn ṣe nyọ̀, ti inu wọn si ndùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn búburú fi àwọ̀n wọn gbé wọn ṣókè ó sì kó wọn jọ nínú àwọ̀n-ńlá rẹ̀; nítorí náà, ó dunnú, ó sì yọ̀ pẹ̀lú.