Habakkuk 2:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
N óo dúró sí ibìkan lórí ilé-ìṣọ́, n óo máa wòran. N óo dúró, n óo máa retí ohun tí yóo sọ fún mi, ati irú èsì tí èmi náà óo fún un.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
LORI ibuṣọ́ mi li emi o duro, emi o si gbe ara mi kà ori alore, emi o si ṣọ lati ri ohun ti yio sọ fun mi, ati èsi ti emi o fọ́, nigbati a ba mba mi wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò dúró lórí ibùṣọ́ mi láti máa wòye Èmi yóò sì gbé ara mi ka orí alóre Èmi yóò si ṣọ́ láti gbọ́ ohun tí yóò sọ fún nu àti èsì ti èmi yóò fún ẹ̀sùn yìí nígbà tó bá ń bá mi wí;