Habakkuk 2:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wò ó, ṣebí ìkáwọ́ OLUWA àwọn ọmọ ogun ni ó wà, pé kí orílẹ̀-èdè kan ṣe làálàá tán, kí iná sì jó gbogbo rẹ̀ ní àjórun, kí wahala orílẹ̀-èdè náà sì já sí asán.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiyesi i, ti Oluwa awọn ọmọ-ogun kọ́ pe, ki awọn enia na ma ṣe lãla fun iná, ati ki awọn enia na si ma ṣe ara wọn li ãrẹ̀ fun asan?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun kò ha ti ṣètò rẹ̀ pé làálàá àwọn ènìyàn jẹ́ epo fún iná kí àwọn orílẹ̀-èdè náà sì máa ṣe wàhálà fún aṣán?