Habakkuk 2:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn OLUWA ń bẹ ninu tẹmpili mímọ́ rẹ̀, kí gbogbo ayé parọ́rọ́ níwájú rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Oluwa mbẹ ninu tempili rẹ̀ mimọ́; jẹ ki gbogbo aiye pa rọ́rọ niwaju rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n OLÚWA wà nínú tẹ́ḿpílì mímọ́ rẹ̀; Ẹ jẹ́ kí gbogbo ayé pa rọ́rọ́ níwájú rẹ.”