Habakkuk 3:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí àwọn òkè ńlá rí ọ, wọ́n wárìrì; àgbàrá omi wọ́ kọjá; ibú òkun pariwo, ó sì gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn oke-nla ri ọ, nwọn si warìri: akúnya omi kọja lọ: ibú fọ̀ ohùn rẹ̀, o si gbe ọwọ́ rẹ̀ si oke.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn òkè-ńlá ri ọ wọn ṣì wárìrì àgbàrá òjò ń ṣàn án kọjá lọ; ibú ń ké ramúramù ó sì gbé irú omi sókè.