Habakkuk 3:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Oòrùn ati òṣùpá dúró ní ipò wọn, nígbà tí ọfà rẹ ń já lọ ṣòòrò, tí àwọn ọ̀kọ̀ rẹ náà ń kọ mànà, bí wọ́n ti ń fò lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Õrùn ati oṣupa duro jẹ ni ibùgbe wọn: ni imọlẹ ọfà rẹ ni nwọn lọ, ati ni didán ọ̀kọ rẹ ti nkọ màna.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òòrùn àti Òṣùpá dúró jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ ni ibùgbé wọn, pẹ̀lú ìmọ́lẹ̀ ọfà rẹ ni wọn yára lọ, àti ni dídán ọ̀kọ̀ rẹ ti ń kọ mànà.