Habakkuk 3:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
O fi àwọn ẹṣin rẹ tẹ òkun mọ́lẹ̀; wọ́n tẹ ríru omi mọ́lẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ fi awọn ẹṣin rẹ rìn okun ja, okìti omi nla.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ fi ẹṣin rẹ rìn òkun já, O tẹ òkun mọ́lẹ̀ pẹ̀lú ẹṣin rẹ̀, ìwọ fi àwọn ẹsin rẹ̀ rin òkun já, ó sì mu omi ńlá jáde okiki omi ńlá