Haggai 1:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìdí nìyí tí ìrì kò fi sẹ̀ láti òkè ọ̀run wá, tí ilẹ̀ kò sì fi so èso bí ó ti yẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ni a ṣe dá ìri ọrun duro lori nyin, a si da eso ilẹ duro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí yín ni awọn ọ̀run ṣe dá ìrì dúró tí ilẹ̀ sì kọ̀ láti mu èso jáde.