Haggai 1:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ni Hagai, òjíṣẹ́ OLUWA, bá jẹ́ iṣẹ́ tí OLUWA rán an sí àwọn eniyan náà pé òun OLUWA ní òun wà pẹlu wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Hagai iranṣẹ Oluwa jiṣẹ Oluwa fun awọn enia pe, Emi wà pẹlu nyin, li Oluwa wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Hágáì ìránṣẹ́ OLÚWA ń jíṣẹ́ OLÚWA fún àwọn ènìyàn pé, “Èmí wà pẹ̀lú yín,” ni OLÚWA wí.