Haggai 1:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà ni OLUWA ṣe rán wolii Hagai sí wọn ó ní,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni ọ̀rọ Oluwa wá nipa Hagai woli, wipe,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ọ̀rọ̀ OLÚWA wá láti ọ̀dọ̀ wòlíì Hágáì wí pé: