Haggai 2:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun ni mo ní kí o lọ bèèrè ìdáhùn lórí ọ̀rọ̀ yìí lọ́wọ́ àwọn alufaa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi; bère ofin lọwọ awọn alufa nisisiyi, pe,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Báyìí ni OLÚWA alágbára wí: ‘Béèrè lọ́wọ́ àwọn àlùfáà ohun tí òfin wí pé: