Haggai 2:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo mi gbogbo orílẹ̀-èdè, wọn óo kó ìṣúra wọn wá, n óo sì ṣe ilé yìí lọ́ṣọ̀ọ́. Bẹ́ẹ̀ ni èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun wí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o si mì gbogbo orilẹ-ède, ifẹ gbogbo orilẹ-ède yio si de: emi o si fi ogo kún ile yi, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò mi gbogbo orílẹ̀ èdè, ìfẹ́ gbogbo orílẹ̀ èdè yóò fà sí Tẹ́ḿpìlì yìí, Èmi yóò sì kùn ilé yìí pẹ̀lu ògo;’ ni OLÚWA àwọn ọmọ ogun wí.