Haggai 2:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Tèmi ni gbogbo fadaka ati wúrà tí ó wà láyé; èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Temi ni fàdakà, temi si ni wurà, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
‘Tèmi ni fàdákà àti wúrà,’ ni OLÚWA àwọn ọmọ ogun wí.