Haggai 2:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ògo tí ilé yìí yóo ní tó bá yá, yóo ju ti àtijọ́ lọ. N óo fún àwọn eniyan mi ní alaafia ati ibukun ninu rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun wí.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ogo ile ikẹhìn yi yio pọ̀ jù ti iṣãju lọ, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi: nihinyi li emi o si fi alafia fun ni, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
‘Ògo ìkẹyìn àwọn ọmọ-ogun ilé yìí yóò pọ̀ ju ti ìṣáájú lọ;’ ni OLÚWA àwọn ọmọ ogun wí: ‘Àti ní ìhín yìí ni Èmi ó sì fi àlàáfíà fún ni’, ni OLÚWA àwọn ọmọ ogun wí.”