Hebrews 1:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gẹ́gẹ́ bí eniyan tií ká aṣọ ni ìwọ óo ká wọn. Gẹ́gẹ́ bí aṣọ, a óo pààrọ̀ wọn. Ṣugbọn ní tìrẹ, bákan náà ni o wà. Kò sí òpin sí iye ọdún rẹ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati bi aṣọ ni iwọ o si ká wọn, a o si pàrọ wọn: ṣugbọn bakanna ni iwọ, ọdún rẹ kì yio si pin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní kíká ni ìwọ yóò ká wọn bí aṣọ, bí ìpàrọ̀ aṣọ ni a ó sì pàárọ̀ wọn. Ṣùgbọ́n ìwọ fúnrarẹ kì yóò yípadà àti pé ọdún rẹ kì yóò ní òpin.”