Hebrews 1:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn ohun tí ó sọ fún Ọmọ náà ni pé, “Ìfẹ́ rẹ wà títí laelae, Ọlọrun, ọ̀pá òtítọ́ ni ọ̀pá ìjọba rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn niti Ọmọ li o wipe, Itẹ́ rẹ, Ọlọrun, lai ati lailai ni; ọpá alade ododo li ọpá alade ijọba rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ó sọ nípa tí Ọmọ rẹ̀ pé, “Ọlọ́run, ìjọba rẹ yóò wà láti ìran dé ìran, àti pé òdodo ni ọ̀pá tí ìwọ fi ń páṣẹ ìjọba rẹ.