Hebrews 10:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Èyí ni majẹmu tí n óo bá wọn dá nígbà tí ó bá yá, Èmi Oluwa ni mo sọ bẹ́ẹ̀, Èmi óo fi òfin mi sí ọkàn wọn, n óo kọ wọ́n sí àyà wọn.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Eyi ni majẹmu ti emi ó ba wọn dá lẹhin ọjọ wọnni, li Oluwa wi, emi o fi ofin mi si wọn li ọkàn, inu wọn pẹlu li emi o si kọ wọn si;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èyí ni májẹ̀mú ti èmi o ba wọn dá lẹ́hìn àwọn ọjọ́ wọ̀nyí, ni Olúwa wí, èmi o fi òfin mi sí wọn ní ọkàn, inú wọn pẹ̀lú ni èmi o sì kọ wọn sí.”