Hebrews 10:38 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn àwọn olódodo tí wọ́n jẹ́ tèmi yóo wà láàyè nípa igbagbọ. Ṣugbọn bí èyíkéyìí ninu wọn bá fà sẹ́yìn inú mi kò ní dùn sí i.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn olododo ni yio yè nipa igbagbọ́: ṣugbọn bi o ba fà sẹhin, ọkàn mi kò ni inu didùn si i.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n olódodo ni yóò yè nípa ìgbàgbọ́: Ṣùgbọ́n bí o ba fà sẹ́yìn, ọkàn mi kò ní inú dídùn sí i.”