Hebrews 10:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ni mo sọ pé, ‘Èmi nìyí. Àkọsílẹ̀ wà ninu Ìwé Mímọ́ nípa mi pé, Ọlọrun, mo dé láti ṣe ìfẹ́ rẹ.’ ”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni mo wipe, Kiyesi i (ninu iwe-kiká nì li a gbé kọ ọ nipa ti emi) Mo dé lati ṣe ifẹ rẹ, Ọlọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni mo wí pé, ‘Kíyèsí i (nínú ìwé kíká ni a gbé kọọ́ nípa ti èmi) mo dé láti ṣe ìfẹ́ rẹ, Ọlọ́run.’ ”