Hebrews 11:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Igbagbọ ni àwọn àgbà àtijọ́ ní, tí wọ́n fi ní ẹ̀rí rere.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ninu rẹ̀ li awọn alàgba ti ni ẹri rere.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí nínú rẹ ni àwọn alàgbà (atijọ́) ní ẹ̀rí rere.