Hebrews 3:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
A rí i pé wọn kò lè wọ inú ìsinmi yìí nítorí wọn kò gbàgbọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awa si ri pe nwọn kò le wọ̀ inu rẹ̀ nitori aigbagbọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwá sì rí i pé wọn kò lè wọ inú rẹ̀ nítorí àìgbàgbọ́.