Hebrews 3:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ rí i pé ó ṣe olóòótọ́ sí Ọlọrun tí ó yàn án gẹ́gẹ́ bí Mose ti ṣe oloòótọ́ ninu gbogbo ìdílé Ọlọrun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹniti o ṣe olõtọ si ẹniti o yàn a, bi Mose pẹlu ti ṣe ninu gbogbo ile rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹni tí o ṣe olóòótọ́ si ẹni tí ó yàn án, bí Mósè pẹ̀lú tí ṣe olóòótọ́ nínú iṣẹ́ rẹ̀ gbogbo ilé Ọlọ́run.