Hebrews 8:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kì yóo sí ìdí tí ẹnìkan yóo fi kọ́ aládùúgbò rẹ̀ tabi arakunrin rẹ̀, pé, ‘Mọ Oluwa.’ Nítorí pé gbogbo wọn ni wọn óo mọ̀ mí, ohun tí ó ṣẹ̀ láti orí àwọn mẹ̀kúnnù inú wọn títí dé orí àwọn eniyan pataki pataki.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Olukuluku kì yio si mã kọ́ ara ilu rẹ̀ ati olukuluku arakunrin rẹ̀ wipe, Mọ̀ Oluwa: nitoripe gbogbo wọn ni yio mọ̀ mi, lati kekere de àgba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Olúkúlùkù kò ní tún máa kọ́ ara ìlú rẹ̀, tàbi olukulùkù arákùnrin rẹ̀, pé, ‘mọ Olúwa,’ Nítorí pé gbogbo wọn ni yóò mọ̀ mí, láti kékere dé àgbà.