Hosea 1:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Hosia bá lọ fẹ́ iyawo kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Gomeri, ọmọ Dibulaimu. Gomeri lóyún, ó sì bí ọmọkunrin kan fún un.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si lọ o si fẹ́ Gomeri ọmọbinrin Diblaimu; ẹniti o loyún, ti o si bi ọmọkunrin kan fun u.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ó sì lọ, ó sì fẹ́ Gómérì ọmọbìnrin Díbíláémù, ọmọbìnrin náà sì lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kan fún un.