Hosea 10:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Efuraimu dàbí ọmọ mààlúù tí a ti fi iṣẹ́ ṣíṣe kọ́, tí ó sì fẹ́ràn láti máa pa ọkà, mo fi ọrùn rẹ̀ tí ó lẹ́wà sílẹ̀; ṣugbọn nisinsinyii, n óo gbé àjàgà bọ̀ ọ́ lọ́rùn, ó di dandan kí Juda kọ ilẹ̀, kí Israẹli sì máa ro oko fún ara rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Efraimu si dabi ọmọ-malu ti a kọ́, ti o si fẹ́ lati ma tẹ ọkà; ṣugbọn emi rekọja li ori ọrùn rẹ̀ ti o ni ẹwà: emi o mu ki Efraimu gùn ẹṣin; Juda yio tú ilẹ, Jakobu yio si fọ́ ogulùtu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Éfúráímù jẹ́ ọmọ màlúù tí a tí kọ́, to si fẹ́ràn láti máa pa ọkà lórí ọrun rẹ̀ tó lẹ́wà ni èmi ó dí ẹru wúwo lé Èmi yóò mú kí a gun Éfúráímù bí ẹṣin Júdà yóò tú ilẹ̀, Jákọ́bù yóò sì fọ́ ogúlùtu rẹ̀