Hosea 10:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ ti gbin ẹ̀ṣẹ̀, ẹ sì ti ká aiṣododo, ẹ ti jẹ èso ẹ̀tàn. “Nítorí pé ẹ gbẹ́kẹ̀lé kẹ̀kẹ́ ogun ati ọpọlọpọ ọmọ ogun yín,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnyin ti tulẹ ìwa-buburu, ẹnyin ti ká aiṣedẽde; ẹnyin ti jẹ eso eke: nitori iwọ gbẹkẹ̀le ọ̀na rẹ, ninu ọ̀pọlọpọ awọn alagbara rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ẹ tí gbìn buburú ẹ si ka ibi, Ẹ ti jẹ èso èké nítorí ẹ tí gbẹ́kẹ̀ lé agbára yín àti àwọn ọ̀pọ̀ jagun jagun yín