Hosea 10:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọn óo máa wí nisinsinyii pé, “A kò ní ọba, nítorí pé a kò bẹ̀rù OLUWA; kí ni ọba kan fẹ́ ṣe fún wa?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori nisisiyi ni nwọn o wipe, Awa kò li ọba, nitoriti awa kò bẹ̀ru Oluwa; njẹ kili ọba o ṣe fun wa?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni wọn yóò wí pé, “A kò ní ọba nítorí tí a kò bọ̀wọ̀ fún OLÚWA ṣùgbọ́n bí a tilẹ̀ ní ọba, kí ni yóò se fún wa?”