Hosea 10:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Dájúdájú, a óo gbé ère oriṣa náà lọ sí Asiria, a óo fi ṣe owó ìṣákọ́lẹ̀ fún ọba ńlá ibẹ̀. Ojú yóo ti Efuraimu, ojú yóo sì ti Israẹli nítorí ère oriṣa rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A o si mu u lọ si Assiria pẹlu ẹbùn fun Jarebu ọba: Efraimu yio gbà itiju, oju yio si tì Israeli nitori igbìmọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A ó gbé lọ sí Ásíríà gẹ́gẹ́ bí ẹ̀bùn fún ọba ńlá a ó dójú ti Éfúráímù; oju yóò ti Ísírẹ́lì nítorí ere òrìṣà rẹ̀