Hosea 11:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA ní, “Nígbà tí Israẹli wà ní ọmọde, mo fẹ́ràn rẹ̀, láti ilẹ̀ Ijipti ni mo sì ti pe ọmọ mi jáde.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NIGBATI Israeli wà li ọmọde, nigbana ni mo fẹ́ ẹ, mo si pè ọmọ mi lati Egipti jade wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nígbà tí Ísírẹ́lì wà ní ọmọdé mo fẹ́ràn rẹ̀, mo sì pe ọmọ mi jáde wá láti Éjíbítì.