Hosea 11:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA ní, “Àwọn ọmọ Efuraimu parọ́ fún mi, ilẹ̀ Israẹli kún fún ẹ̀tàn, sibẹsibẹ mo mọ ilé Juda, nítorí pé ó jẹ́ olóòótọ́ sí èmi, Ẹni Mímọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Efraimu fi eke sagbàra yi mi ka, ile Israeli si fi ẹtàn sagbàra yi mi ka: ṣugbọn Juda njọba sibẹ̀ pẹlu Ọlọrun, o si ṣe olõtọ pẹlu Ẹni-mimọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Éfúráímù tí fi irọ́ yí mi ká ilé Ísírẹ́lì pẹ̀lú ẹ̀tàn. Ṣùgbọ́n Júdà sì dúró ṣinṣin pẹ̀lú Ọlọ́run Ó sì ṣe olóòótọ́ sí Ẹni mímọ́ Ísírẹ́lì.