Hosea 11:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn bí mo ti ń pè wọ́n tó, bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n ń sá fún mi, wọ́n ń rúbọ sí àwọn oriṣa Baali, wọ́n ń sun turari sí ère.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi nwọn ti pè wọn, bẹ̃ni nwọn lọ kuro lọdọ wọn: nwọn rubọ si Baalimu, nwọn si fi turari joná si ere fifin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n rúbọ sí Báálì bí mo ṣe ń pe Ísírẹ́lì sí bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe ń sá kúrò lọ́dọ̀ mi jìnnà sí i: wọn rúbọ sí báálímu, wọn sì fi tùràrí jóná sí ère fínfín.