Hosea 11:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bẹ́ẹ̀ ni èmi ni mo kọ́ Efuraimu ní ìrìn, mo gbé wọn lé ọwọ́ mi, ṣugbọn wọn kò mọ̀ pé èmi ni mo wo àwọn sàn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mo kọ́ Efraimu pẹlu lati rìn, mo dì wọn mu li apa, ṣugbọn nwọn kò mọ̀ pe mo ti mu wọn lara dá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lóòtọ́ mo kọ́ Éfúráímù pẹ̀lú ní ìrìn mo di wọ́n mú ní apá, ṣùgbọ́n wọn kò mọ̀ pé mo ti mú wọn lára dá.