Hosea 12:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Mo bá àwọn wolii sọ̀rọ̀; èmi ni mo fi ọpọlọpọ ìran hàn wọ́n, tí mo sì tipasẹ̀ wọn pa ọpọlọpọ òwe.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi ti sọ̀rọ nipa awọn woli pẹlu, mo si ti mu iran di pupọ̀, mo ti ṣe ọ̀pọlọpọ akàwe, nipa ọwọ́ awọn woli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo sọ fún àwọn wòlíì, mo fi ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ìran hàn wọ́n mo sì pa òwe láti ẹnu wòlíì wọn.”