Hosea 12:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA ní ẹjọ́ tí yóo bá àwọn ọmọ Juda rò, yóo jẹ àwọn ọmọ Israẹli níyà gẹ́gẹ́ bí ìwà wọn, yóo sì san ẹ̀san iṣẹ́ ọwọ́ wọn fún wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa ni ẹjọ kan ba Juda rò pẹlu, yio si jẹ Jakobu ni iyà gẹgẹ bi ọ̀na rẹ̀; gẹgẹ bi iṣe rẹ̀ ni yio san padà fun u.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA ní ẹ̀sùn tí yóò fí kan Júdà yóò fìyà jẹ Jákọ́bù gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà rẹ̀ yóò sì sán fún-un gẹ́gẹ́ bí i ìṣe rẹ̀.