Hosea 12:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jakọbu, baba ńlá wọn di arakunrin rẹ̀ ní gìgísẹ̀ mú ninu oyún, nígbà tí ó dàgbà tán, ó bá Ọlọrun wọ̀jàkadì.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O di arakunrin rẹ̀ mu ni gigisẹ̀ ni inu, ati nipa ipá rẹ̀ o ni agbara pẹlu Ọlọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti inú oyun ni ó ti di arákùnrin rẹ̀ mú ni gìgísẹ̀, àti nípa ìpá rẹ̀ ó ni agbára pẹ̀lú Ọlọ́run