Hosea 12:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, ẹ yipada nípa agbára Ọlọrun yín, ẹ di ìfẹ́ ati ìdájọ́ òdodo mú, kí ẹ sì dúró de Ọlọrun yín nígbà gbogbo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina, iwọ yipadà si Ọlọrun rẹ: pa ãnu ati idajọ mọ, ki o si ma duro de Ọlọrun rẹ nigbagbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ìwọ́ gbọdọ̀ padà sọ́dọ̀ Ọlọ́run rẹ̀; Di ìfẹ́ àti ìdájọ́ òdodo mú kí ẹ sì dúró de OLÚWA yín nígbà gbogbo.